Itoju Pajawiri
Danger (Ewu) – Ki a rii daju wipe agbegbe ni wa lai l’ewu. Ki a ri daju wipe oju ona dara. Ki a tun rii daju wipe ko si ina ni tosi, Bi a ba lee gbe eni naa, ki a rii daju wipe a gbe eni naa losi ibi ti yoo ti ri iwosan pajawiri. Eleyi yoo se iranlowo fun eni be.
​
Response (Idanhun) - nje eni naa lee s’oro bii? Nje eni naa lee da eniyan mon? Bawo ni won se mon o? Nje eni naa fi ori gbale ni bi? Nje won si nmi eemi? Eje ki a rii daju wipe eni naa dawa mo lati dena iku ojiji.
Nibayi, e je ki se ayewo boya won lee joko, boya eje n jade l’ara eni naa, nibo ni ipalara naa ti n jade wa? Irufe awon iranlowo pajawiri yii lee se iranlowo. A ko nilo isise ABC, sugbon a lee gbe won lo si ile iwosan.
​​
Airway (Afefe) Bi oju eniyan ba n poyi tabi eje n da l’ara oni tohun gidigidi, o se pataki ki a fi eyin oni tohun le ile. E je ki a ri daju wipe won ri aye lati mi eemi ki a si fi ori won si ipo to dara. Bi eni naa ko ba mi eemi wole tabi jade, e je ki a se ayewo boya nkan sa pamo si ona ofun oni tohun, eyi ti ko je ki won ri aye mi eemi.
​
Breathing (Eemi): Boya won ni isoro pelu mimi eemi tabi eemi won l’agbara ju boti yelo. E je ki a se iranlowo lati ri daju wipe won n mi eemi bi oti to ati bi oti ye.
Circulation (kaakakiri) Nje won n mi eemi wole ati jade?
​​
------------------------------------------------------------------------------
Choking: Bi eniyan o ba se deedee, o se pataki ki a se awon nkan wonyi:
1. Ki a da eni naa wa si egbe
2. Ki a fi atelewo gba aarin eyin oni tohun
Tabi
1. Ki a naro si eyin eni na ki a si fi owo gba egbe oni tohun mi
2. Ki a fi omo ika te There are some very simple tricks to try when a person starts choking. First, it is usually safe to assume that the person has something stuck in their throat.
3. Ki a fi omo ika te egungun egbe ati idodo. (Bi eni naa ba je aboyun, omode, tabi ro lapa/lese, o se pataki ki a fi owo te igba aya won lalai fowo kan inu won)
4. Fi owo te inu eni naa lojiji pelu agbara. Eleyi yoo je eemi jade wa lati inu fuku eni nas.
Oju apa
1. Da omi ti o mon si oju e lesekese. Omi naa gbodo loworo tabi omi inu igo. Omi ti o ba ni Idoti lee se ijanba. E je ki a maa daa omi naa si fun iseju mewa
2. Ti nkan ba wa loju e, ki a ma se mu kuro. Eje ki a fi sile bee.
Ti o ba seese, ki a mu aso kuro loju e tabi ohun kohun ti o wa l’oju egbo naa. A ko gbodo fi omi tutu tabi lo ohun isese.
Cuts (Oju ogbe)
1. Ti oju ogbe naa ba jin, o se pataki ki a ba eni naa tee pelu aso. Eyi lee fa opolopo irora, sugbon yoo san eje naa duro.
2. Bi eni naa ko ba le tee, o se pataki ki a baa see. A gbodo sora nitori aisan inu eje eni lati ma ran wa. E je ki a fi nkan da abo bo owo wa.
3. A gbodo fi omi ati ose fo oju ogbe naa. Eni naa gbodo ri daju wipe gbogbo nkan ti o wa loju ogbe naa jade kuro bi eni ko ba fe lo si ile iwosan.
IBA:
je aisan eleyi to wopo laarin awon omo wewe. Awon nkan ti a lee se leyi ni asiko iba :
1. Ki a fi aso bowon lara die.
2. Ki a ri daju wipe ategun n fe wole siwon l’ara
3. Ki a fun eni naa ni oogun Paracetamol. Eleyi ko gbodo poju.
Opolopo omi. Ti eni naa ba n bi ebibi tabi se igbonse lopo, e je ki a fun won ni omi ti o mon mu.
4. Ki a fi eni naa si ibi ti o tutu. Ki a bo aso kuro l’ara eni naa ki a si fe ategun sii
5. Ki a da omi si ara eniyan naa. Ki a fi aso tutu si ara eni naa ki a si fe ategun sii
6. Ki a fun eni naa ni omi ti o loworo mu





PAJAWIRI 101

