
Awon Aisan Ti O Wopo
Iba, Atogbe, Igbonna
​
Nje o lee d’aruko awon aisan ti o wopo? Bawo ni a se lee ri Dokita ati bi a se nse itoju aisan awon aisan naa? Iwadi ti fihan wipe awon aisan bii iba, ori fifo, atogbe igbonna, ara riro ati beebee lo wopo l’awujo .A o maa se alaye awon aisan naa ni eyokookan.
Awon ona ti a lee gba lati ko nipa aisan orisirisi se iyebiye. Ona kan ni lati maa se alaye nipa aawon aisan naa ni ona igbese naa:
1. Kinni: Kinni ohun ti o fa aisan naa?
2. Bawo ni eniyan se ni aisan naa/nibo ni aisan naa ti wa?
3. Aami: Kinni awon aamin aisan naa?
4. Itoju: Bawo ni a o se s’etoju aisan naa?
5. Idena: Bawo a o se d’ena aisan naa lati ma lee ran awon eniyan?
​
Bi a se n ko nipa awon aisan yii, e je ki a fi s’okan bi a se nsetoju won, ki a si tun maa ranti wipe “ilera l’oro”
​​
IBA
Kinni ohun ti o n fa iba ni kokoro lati inu eje tabi Awon efon a maa fi aisan si eniyan l’ara nipa mimu eje eniyan. Bakana, Oorun kii fa aisan iba.
Aamin
Iba ti ohun wa ti o si tun lo
Gbigban ati oogun
Irewesi
Ailera
Egun didun
Isan ara a maa r’oni asitun maa tu eniyan l’ara
Itoju
Ogun oni koro meji bii CoArtem. A maa n lo Chloroquine, sugbon asilo ogun naa ko je ki o se ise bi o ti to ati bi oti ye. Awon egboogi ibile naa a maa sise bi a ba lo ni iwonba ati ni asiko ti o ye.
​​
Ideba
Bibo ati Pipamo: Efon a maa ye eyin si inu omi. E je ki a maa pale omi wa mo ki a si tun maa se eto abo re. Efon a maa fe lati maa je eniyan ni ale. I se pataki ki a maa da ile nu lakoko ti o ye.
E je ki a maa fin ogun efon s’inu ile ki a si maa ti ilekun ati
​
Aso oni’ho: Ki a rii daju wipe aso efon naa ko ni iho rara. Ki a kii bo egbegbe ibusu wa. Ki a tun rii daju wipe a ko fi ara kan aso efon naa.
Ona kan soso ti a fi lee mo wipe eniyan ni aisan iba ni nipase ayewo. Ayewo naa pin si ona meji:
RDT (rapid diagnosis test): Ayewo Onidanwo Kiakia je eyi ti ao lo eje eniyan lati omo ika ti ao si daa pada laarin iseju 15-30. Awon ti ko ni omi ijinle nipa eto ilera lee mo nipa bi a se s’etoju aisan iba.
Ayewo eje: Eleyi tun je ona ti a lee fi mon awon oni’mo ijinle nipa eto ilera. Awon oni’mo nipa eto ilera lai maa lo irinse igbalode lati se ayewo ara eniyan.
IJIRORO: Kinni idi ti awon eniyan kan se ni igbagbo wipe oorun a maa fa iba? Bawo ni a se n da irufe awon eniyan naa lohun?
IDARAYA: E pin ara yin. E se idaraya pataki ki a se ayewo ki a to lo ogun iba.
IJIRORO: Bawo ni awon eniyan se n se itoju ara nipa lilo ogun ibile? Nje awon ona dara bi?
​​
ATOGBE
Awon nkan ti o n fa atogbe ni aisan ti o n pa fuku l’ara. Atogbe a maa w’aye nipase iko, sisi’to ati sinsin ito. Atogbe je aisan ti o n ran. Eni ti o ba ni atogbe gbodo maa fo owo re deedee Onitohun gbodo maa tele ohun Dokita ba wi.
Aamin
Iko wiwu olojo gbooro eyi ti o buru jai
Eyin didun
Aya didun.
Ailera
Awon aamin ti o tun l’agbara ni wiwu iko eleje, ohun tiinrin, eran ara to n se segesege.
Itoju
Orisirisi atogbe ni o wa. O se pataki fun eniyan lati y’ojusi Dokita fun imoran ati itoju. Ni orile ede Nigeria, ofe ni ayewo sugbon eniyan lee san owo fun awon irinse ti a lo. Ni igba miran, a maa to bi osu mefa ki Eniyan to ri itoju. .
​​
Ide'na: Eni naa gbodo maa fi owo bo enu ti o ba n wu iko. Eni naa ko gbodo tu ito s’ile .Bi iru awon apere yii ba sele laarin ose meji si meta, o se pataki ki eni naa lati y’ojusi Dokita. A gbodo se itoju fun awon ebi won si gbodo maa sun lotooto titi ara eni naa yoo fi ri iwosan Awon oogun naa wa fun awon omode ti a n pe ni BCG. Ogun naa kii sise fun agbalagba sugbon oun sise fun awon omode.
.
ISE SISE: Itoju olojo gbooro le e je ki eniyan lee tete duro. Ki eniyan meji se bi eni ti n ba awon eniyan jiroro nipa anfani ti o wa ninu ki a maa lo oogun pari
IJIRORO: Awon ona isemb’aye wo ni a fi n se itoju arun atogbe? Nje sise bee ko l’ewu?
​​
AKO IBA:
Kinni ohun ti oun fa Ako Iba ni kokoro ti se ipalara fun ago ara eniyan. Bi a ko ba fo owo leyin ti a ba kuro ni ile igbonse, sugbon ti a fi owo naa jeun, eniyan lee ni arun Atogbe. Omi ti o ni igbonse ninu naa lee fa a ati jije ounje ti a ko do daadaa.
Apere
Iba. Ori fifo
Egbo on'ofun
Iko wiwu
Ailera ati gbigbon
Aini ipinnu
​
Itoju
O se pataki ki a se ayewo ako iba ki a to lo oogun atogbe. Bi eniyan ba n yo orisirisi awo l’ara, eni naa gbodo lo ri Dokita.
​​
Idena re: Gbiyanju lati ri daju wipe ile igbonse ko si ni tosi ibi a ti omi mimu wa. Ki a ri daju wipe a fo owo nu leyin ti a ba ti jade kuro ninu ile igbonse. Ki a ri daju wipe a se omi ti a n mu ati eyi ti a fi n da’na. Ogun ako iba lee wa gege bi ogun olomi tabi ogun onikooro
SKIT: Olukoni yoo wi fun awon meji lati kopa gege bi eni ti o n se aisan. Won yoo se alaye bi won se n bi ara won se rii.
Lalai ba awon alajogbepo jiroro, se alaye nkan ti enikinni ati enikeji ni. Jiroro l’ori esi abajade naa.
IJIRORO: Awon ona wo ni awon eniyan ngba se itoju ako abi? Nje awon ona wonyi ko l’ewu ? Eleyi wopo laarin awon omod
​​
IGBONNA
Kinni ohun ti oun fa igbonna ni awon kokoro ti o mba awon eroja inu ara ti a fi n mi ja. Eleyi wopo laarin awon omode nipase airi ounje afara lokun je. A lee ri apere re nipase iko wiwu, sinsin ati if’enu k’onu .Eniyan tun lee ni nipase fifi owo kaan.
Apere
Iko, imun rirun, awon nkan funfun a maa wa l’ori ahon. Eleyi a maa tan kakakiri.
​​
Itoju
Awon ogun agbogun ti aisan lile miiran kii sise fun igbonna. Nitori idi eyi, ki eniyan maa sinmi, jeun, mun opolopo omi, je eyin, Vitamin A eyi ti yoo je ki omo ni okun ati agbara.
​​
Ide'na Ki awon omode maa fo owo won leyin ti won ba ti jade kuro n’ile igbonse. Ki won tun maa fo owo won ki won to jeun ati leyin ti won ba jeun tan. Ki won maa jeun af’ara l’okun. Awon ona wonyi ni a lee gba lati d’ena aisan ati awon arun.
Idaraya: Piin ,ki e si s’eto orin l’ori bi a ti n se itoju ati idena igbonna. E korin naa. Nibayi, tani o j’awe olubori?
IJIRORO: Awon ona isemb’aye wo ni a n gba lati lee s’etoju aisan iba? Nje irufe awon ona yi dara?
IGBE GBUURU
Kii kokoro orisi kan ni o n fa igbe gbuuru. Apere orisi ailera ni o je. Jije ounje ti ko dara ati ailera ni o n faa. Bi eniyan ba ni aisan igbe gbuuru, ara eni naa a maa fa omi lati eya ara miiran, asi maa jade lati ifun kekeeke. Ti ara eniyan ba ti da omi nu ju, gbogbo eya ara eniyan yoo d’awo ise duro eni naa yoo si ku nipase aito omi ara.
Dakuko awon ohun ti o n se okunfa igbe gbuuru:________________________________________________________________________________________________________________________________________________________________________________
Igbe gbuuru wopo. Awon eniyan a maa ni ni igbagbo, sugbon bi a ko ba se itoju e, o lee s’eku paniyan. O je okan ninu awon aisan ti o s’eku pa awon omo wewe.
Itoju
Maa mun omi, je ounje ti o ti ko ki ju bii iresi ti o san, ewa tabi eran, miliki, eyin, iyan ti o san, ogede ati beebee lo. A ko gbodo mun oti lile tabi je ounje ti o ni adiagbon ju.
Ide’na
Ounje gidi ati omi mimo nikan ni o lee d’ena igbe gbuuru laarin awon omode. A tun gbodo maa fo owo wa n’igba gbogbo. Eleyi se pataki.
​​
Idaraya: E pin yara naa si egbe meji. Oluko ni yoo ka ibeere ati oro jade. Eyi ninu awon egbe ti o ba dahun ibeere ni yoo j’awe olubori.
​​
ISE SISE: Se alaye bi a ti n koju oogbe. Ko awon egbe bi a ti n ko nipa awon ohun ti o n d’ena aito omi. Eniyan meta yoo se bi a ti n dojuko aito omi ninu ago ara eniyan.

.jpg)




