top of page

Eto Ara Eni Gbogbo

Eyi je ikeko lori eya ara eniyan ati bi won se nsise. Orisirisi eya l’owa lara wa pelu ojuse otooto. 

​

Egungun Ara Eniyan

Egungun: Awon egungun ti o so po ninu ara eniyan je ohun ti o je ki o seese fun eniyan lati maa rin lati ibikan titi de ibomiran. Bakana naa ni egungun n daabo bo ara wa. Ohun naa loje ki o seese lati maa se nkan gege bi eniyan.

Eegun: Eleyi ni o le ju nuni ago ara eniyan. Ohun loje ki o seese fun eniyan lati maa sa ere, jeun, jo ijo, fo s’oke ati beebeelo. O se pataki lati fi oju kan Dokita ti eegun eniyan ba kan tabi da:

Egun Ori: Eleyi je egun ti o n da aabo bo ori ti o si n fun ori ni igun ti o see wo

​

Eegun egbegbe: Eleyi je egun mejila (12) ti o n da aabo bo edo-fooro

​

Egun isopo: Eleyi je ibi ti awon egungun ti pade .

​

Kere-kere: Eleyi je egun ti ko ni agbara lo titi. Ohun da aabo bo imu ati eti.

​

Egun Riki-riki Ara

Egun riki-riki je eyi ti o wa ni ibi awon ti o nipon l’ago ara eniyan. Bi eniyan ba ko jale ti ko lo egun riki-riki ara, awon egungun naa yoo siti. Bakana, bi eniyan ba lo egungun riki-riki ara ju bo ti ye lo, a maa gba agbara l’owo egungun riki-riki ara eniyan.

​

​
Ohun Ti O Doti N Gbe Eje Kaakiri Ara

Eleyi je ohun ti o n gbe eje kaakiri ara eniyan. Okan, ile eje, isan ara ati beebeelo je awon nkan eya ara ti o gbe eje kaakakiri.

 

Eje n gbe afefe kaakakiri gbogbo inu ago ara eniyan. Eje tun s’eto awon eroja ti o mon ba awon aisan ati kokoro ja ninu ago ara eniyan.

 

Irufe Eje:Orisirisi eje lowa l’ara eniyan, o si se pataki ki eniyan mon irufe eje ti o wa l’ara re: A, B, AB, and O. Bi eniyan ba ni IV, o seese ki a fi ife si inu isan ara. Ohun ti a n pe ni IV lee gbe omi niwontun wonsi ti eniyan ko ba lee mu omi ti o to. Bakana, a tun lee fi ogun si inu isan ara. Eyi lee je ki ogun naa ki o se ise l'akoko.

 

Okan: Isan je ohun ti o n faa ti eje se nlo kaakakiri gbogbo ara eniyan. Okan ati edo-foro n se ise papo lati lee je afefe gba okan wa wole ati jade ati lati lee d’ena awon irufe aisan. Eniyan lee ni aisan okan ti eje iru eni bee ba ni aisan.

​

Eya Opolo Eniyan

Eleyi ni se pelu opolo eniyan. Opolo ni ohun je ki eniyan lee ro’nu. Opolo ni ohun je ki a r’onu. Ohun naa ni ohun je ki a mon bi ebi ba n pani

 

Opolo: Opolo ni o n je ki a se ipinnu. Bi ohun kohun ba sele ni ago ara eniyan, opolo ni yoo so fun ta wa l'olobo. Opolo ni o fun wa ni anfani lati ri, gbo oorun, gbo, towo ati lati maa rin. It also controls our body – Ohun naa ni o je ki a maa mi, s’eju, s’oro ati beebee lo. Egun ori n da aabo bo opolo wa. Idi niyi ti o fi je wipe ti ohun kohun ba sele si opolo tabi egungun ori, eyi maa n pa eeya ara miran lara.

​

Eya Ti A Fi N Mi Eemi

Eyi ni a n pe ni Respiratory System ti a fi n mi eemi s’inu ati s’ita. Nipase Fuku.. Bi a ko ba lee mi daada, eleyi maa n je ki gbogbo eya ara eniyan wa l’oju kanna.

 

Fuku: Awon wonyi ni won gbe eemi wole ati jade. Egungun egbe ni o n da aabo bo Fuku. Idi niyi ti o fi seese lati se itoju aisan ara ju inu eje tabi ifun eniyan ko.

 

Trachea: Eyi ni opa afefe ti n gbe afefe lo si oke s’inu fuku ti o si maa n pin si meji lati yipada di Bronchi.

​

Eya Ti O N Jeki Ounje Da

Eya ti ohun je ki ounje da n’inu p’orisirisi biu enu, Ikun, Ifun, Ile Ito ati beebee lo.

 

Enu: Enu je ona kan gboogi ti aisan lee gba wole sinu ara eniyan nipa fifi owo ti o doti s’enu, jije ounje ti ko jinna, mimu omi ti o doti ati beebee lo. Eniyan lee se aisan bi ko se itoju enu re paapa julo eyin. Awon ti won se aisan eyin maa b se aisan deedee nipase eyin won ti o doti.

 

Inu: Eleyi ni ohun se eto bi ounje se n da n’inu eni. Yoo sodi ohun ti o fele ki o to lo s’inu ifun. Orisi ifun meji ni a ni: ifun kekere ti ohun je ki ounje da ati ifun ninla eyi ti ohun fi aaye gba igbonse. Bi eniyan ba je ohun ti ko dara, ara eniyan yoo tii opolopo omi losi inu ifun eniyan, eleyi ti yoo yori si ki eniyan maa ymse igbonse ni gbogbo igba.

 

Ile Ito: Kidirin maa n dari awon ohun olomi ti ko dara losi ile ito. Ara a maa dari awon idoti jade kuro l’ara eniyan ni awon ona bii oogun, mimi eemi inu jade, sise Igbanse, tito ito ati beebee lo. Awon idoti yii a maa wa ni awon ona bi nipase sise Igbanse tabi tito ito jade.

​

bottom of page