top of page

Abere Aje S'ara

Lagos, Nigeria

VACCINATIONS

Ni orile ede Nigeria, eto abere aje s’ara je ofe fun awon omo odun Marun. Awon Dokita ni awon itele lati fun awon omo wewe ni abere aje s’ara. Awon obi naa gbodo ni kaadi abere aje s’ara fun awon omo wewe. Eleyi yoo je ki Dokita mon irufe abere aje s’ara ti o ye fun irufe omode Eleyi tun se pataki lati je Dokita mon igba ati akoko ti o ye ki omode naa gba abere aje s’ara

Bi Dokita ba ko jale lati fun abere aje s’ara lofee, e lee kan si EI paralegal.

HIV/AIDS INFORMATION

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

 

INFANT/MATERNAL MORTALITY

GOOD MEDICAL PRACTICES

RISK FACTORS FOR ADULTS IN NIGERIA

bottom of page