Eto Si Ilera 101
​
CHEs ati Paralegals lee sise papo lati ri daju wipe awon eniyan je anfani eto ilera ti won l’eto si labe ofin bii eto pajawiri ati beebeelo. Eto si ilera tunmo si wipe eniyan gbodo lee je anfani eto ilera l’eye osoka. Anfani ilera naa gbodo k’opa takun-takun l’ori ilera eniyan naa. A lee pin awon ofin l’ori eto ilera si ona merin:
​
Eto Ilera Alakobere: Eleyi je alakoko ti o se pataki. Awon eleto ilera ilu, awon oloogun se pataki lati se ayewo si ago ara eniyan, lati s’ayewo si awon nkan bii egbo, oju apaa, ialera, eto oyun nini, Eto ilera alakobere je ohun to se pataki lati Bakana, ofe ni
Eto Ilera Eleekeji: Eleyi le die, o si se pataki ki a se ayewo si awon aisan bii aisan okan, aisan jejere ati beebeelo.
Eto Ilera Alada Nla: Eleyi naa l’agbara pupo osi se pataki ki a lo awon ero ijinle lati se ayewo. Gbogbo ile iwosan ko ni won nse eto ilera alada nla. Bakana, eto ilera alada nla a maa ni owo ninu.
Eto Ilera Pajawiri: Eleyi ni se pelu aisan pajawiri eyi ti o nilo itoju nla ati pajawiri.. Bi a ba losi ibi ti won ti nse eto ilera pajawiri, ofin so wipe ki awon eleto ilera pajawiri se itoju enikeni ti o ba je olufarapa naa l'eye osoka.
Awon Ofin Ni Ilu Eko:
Awon ofin eto ilera ti ilu: Eko eyi ti a gbe yewo
-
Awon omo ti won o ju odun mejila lo;
-
Agbalagba (60+);
-
Oni ‘se ijoba; ati
-
Awon alaini
Won le gba iwosan ofe ni ile iwosan ijoba. – Ofin ko fi aye gbaa lati ma se itoju enikeni ti ko ba l’owo l'owo, eleto ilera ko gbodo se eto ilera lai gba’se lowo eni ti o n fe iwosan.
Ofin Eto Abere Aje S'ara
A ko gbodo se alase iwosan fun eniyan paapa julo omo alaini lawujo
​
Ajo Ti Ohun S’eto Ilera Fun Iba
Enikeni ti o ba lo si ile iwosan ijoba yoo gba iwosan ofe, sugbon yoo san owo ayewo
​
Ajo To N Se!’eto Iko Ife ati Ete
Ofe ni oogun ati ayewo fun awon ti o ni Iko Ife. Kii se ofe ni ibeni wo
​
Ajo Ti Ns'Ofin Nipa Arun Ko Gbo’gun
Ofe ni oogun, abewo ati ayewo. A ko gbodo d’eye si won a si gbodo se oro ailera won ni oku oru.



Eto Si Ilera

