top of page

Omi Ati Imototo: Bi Arun Se N Wo Inu Omi

·        Igbanse ati Ito: Omi lee di ohun ti o doti ti Igbanse ba wo inu omi naa. Eleyi n sele pelu adagun odo, Bakana, eyi tun le sele pelu omi ti ohun san. Nigba ti aisan bii iba tabi arun onigba-meji ba wo inu omi, aisan lee wo inu ara eniyan. Awon eranko naa lee fa ohun ti a n pe ni diarrhea.

·        Idoti ati Kemikali: Bi eniyan ba n gbe ni ayika eyi ti won ti n po kemikali, ti kemikali naa si fe wo inu omi, eyi lee fa aisan fun enuyan- eyi lee fa eje riru ati isoro oyun nini.

·        Oku eranko: Awon eranko ti o ti ku naa lee fa aisan ti eya ara won ba fe wo inu omi. Tabi bi eranko ba ye eyin si inu omir. Ni opo igba, awon kokoro naa lee dagba si inu omi, eyi ti o le fa inu rirun tabi aida ounje paapa julo leyin ti a ba lo omi naa. Bi awon kokoro naa ba je wa, won tun lee fa aisan ti inu ago ara wa - gege bi efon ti n fa aisan iba s’inu ago ara eniyan. Awon ohun ti a n da panti si tun le fa aisan inu omi.

Bi A Sele Se Eto Ilera Ti O Muma D’oko:

·        Koki ile iyagbe: Awon kokoro ti o n fa aisan a maa wa nipase ile Igbanse. Eyi lee sele ni opolopo ona bii ki eniyan maa fo owo leyin ti o ti lo si ile igbonse, sise Igbanse si ibi ti awon eniyan ti n pon omi mimu, nipa Igbanse eyi ti agbara gbe wole. Awon ona kan gboogi lati d’ena asian ni ki a ko Ile igbonse Eyi yoo fi opin si ki eniyan maa se Igbanse kaakakiri paapa julo si inu omi eyi ti ombe ni ayika.

​

·        Mimu omi ti o mon gaara: Awon Ajo Isokan Agbaye ati Ajo Eleto Ilera Agbaye ti soo di mimi wipe eniyan ni eto si omi ti o mon geere ati ilera ti o dara. Mimu omi ti o dara je ona abayo lati d’ena aisan ni agbegbe wa.

​

Bi A Se Nse Eto Ilera Ara Eni

·        Wiwe Ara Eni Ni Gbogbo Igba: Bi o ba seese, gbogbo eniyan gbodo maa we ni ojojumo, bi o ti lee je pe eleyi ko seese. Fun apere, bi eniyan ba jade kuro ninu ipago, o ye ki a lo karinkanrin lati fo ara wa

​

·        Fifo enu ni eekan l'ojumo: Fifo enu leyin ounje je ona ti a lee gba d’ina aisan eyi ti o le t’ipase enu mu ni. Nitori idi eyi, o se pataki ki eniyan fo enu leyin ti o ti je ounje ale

​

·        Fifo irun ori pelu ose shampoo ni eekan laarin ise

​

·        Fifo owo leyin ti eniyan ba jade n’ile igbonse j

​

·        Fifo owo wa ki a to s’eto ounje ati leyin ounje: Nipase ise oojo wa, aisan lee gba’be w’onu eekanna ati owo wa. Bi a ko ba fo awon kokoro naa danu kuro ni owo wa, aisan lee gba’be w’ole .

·        Wiwo aso ti o dara: A gbodo maa wo aso ti o dara lati d’ena aisan

·        Sisa aso si inu Oorun: Itankale Oorun naa yoo pa awon aisan ti o wa ni ara aso naa

·        Eniyan tun gbodo maa fi owo bo enu ti o ba n wu iko: Bi ko ba ri be, awon aisan lee gba imu tabi enu jade si ara elomiran.

Omi lee di ohun ti o doti ti Igbanse ba wo inu omi naa. Eleyi n sele pelu adagun odo, Bakana, eyi tun le sele pelu omi ti ohun san. Nigba ti aisan bii iba tabi arun onigba-meji ba wo inu omi, aisan lee wo inu ara eniyan. Awon eranko naa lee fa ohun ti a n pe ni diarrhea.

bottom of page